Ileri Se
Imoleayo Bright
Struggling with Ileri Se? Become a better singer in 30 days with these videos!
Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Awa o korin ayo Fore toluwa se fun wa Akaikatan lore baba o Ninu aye wa O da wa lare O se wa logo o A o se ni dupe A o se ni korin A tun jijo ope fun olorun Awa o korin ayo Fore toluwa se fun wa Akaikatan lore baba o Ninu aye wa O da wa lare O se wa logo o A o se ni dupe A o se ni korin A tun jijo ope fun olorun To mu ileri ise Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri ayo Ileri ogo Ileri igbega Ti olorun da fun mi o O ba boju wole mu ileri re se Asiko ti to Olorun da majemu pelu wa O mu leri se Ore gbo Ma se so ireti nu Majemu ti baba ba o da O wa sibe Akoko na de Lati mu leri se fun e Ore tuju ka Baba yio mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Wa muse Ileri ayo to ba mi da O di dandan Ko muse ninu aye mi Ni Isreali O mu ileri se iyanu lo je O mu won la Okun pupa ja O mu ileri se Ni ile samaria Lo mu ileri se Iyefun kan A ta ni shikeli kan Onileri ayo Orile ede wa di owo re Bawa tun se Kaiye de wa lorun Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ileri se Ileri se oh oh adupe Olorun da majemu pelu wa O mu ileri se Ore to se fun wa o por o A o le pa mora Awa a dupe A tun sope f'eleruniyin Ore to se lori aye wa A o le pa mora Awa a dupe A tun sope f'eleruniyin Ore to se fun wa o por o A o le pa mora Awa a dupe A tun sope f'eleruniyin Ife re lori wa por o A o le mu mora rara Awa a dupe A tun sope f'eleruniyin Ore to se fun wa o por o Opor opor ko mama l'akawe Awa a dupe A tun sope f'eleruniyin
Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Ileri Se Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 21 Jun 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8783971/Imoleayo+Bright/Ileri+Se>.
Discuss the Ileri Se Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In