Elédùmarè
Sheun Natural
The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com
Eniyan on se Elédùmarè Say GoGo Ninu ofii ninu ola omo Pandoro n dagba Mo dupe Baba Ero ota Lori mi ti dasan Temitope Baba Eni ta ti ro pe kole pago N'kole alaja mefa Mo m'ope mi wa ewa bamiyo E k'halleluyah meta ehh Gbogbo aye e dide E gbohun soke Eyin ara mi e dide E korin soke oh Elédùmarè Elédùmarè Elédùmarè yeh yeh Elédùmarè Ahhh ahh Ahh rih ahhh Ahh ahhh ehhh ahh Ariba Sese ninu mi dun Ayo kun'nu okan mi o Hmmm hmm Hmm mm Sese ninu mi dun Ayo kun'nu okan mi oo Ooooo Oooh ohhh Mayo mayo mayo Oluwa lo se mi logo Mayo mayo mayo Emi gan gan l'omo ologo Mayo mayo mayo Emi gan gan ni GOGO Uhhhhhh Gbogbo aye e dide E gbohun soke Eyin ara mi e dide E korin soke oh Elédùmarè Elédùmarè Elédùmarè yehhh Elédùmarè Sheun Natural yeah Oshey Drimz Ninu ofii ninu ola omo Pandoro n dagba Mo dupe Baba Say GOGO
The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Elédùmarè Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 25 Sep. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/6337119/Sheun+Natural/El%C3%A9d%C3%B9mar%C3%A8>.
Discuss the Elédùmarè Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In