Gbekele
Jumoke Omotoso
The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com
Uh uh Eh Eh Oh oh oh Oh oh Oh oh ah ah Gbekele Ojo tipe to ti n reti iyanu O ti gbiyanju Oti se'won to lese Sugbon ma so ireti nu ranti eleda re Gbekele yi o gba o Ojo tipe to ti n reti iyanu O ti gbiyanju Oti se'won to lese Sugbon ma so ireti nu ranti eleda re Gbekele yi o gba o Jesu n gbala Jesu n wo San Iwo sa ti gbagbo Gbekele ko ro mo Yi o wa pelu re Jesu n gbala Jesu n wo san Iwo sa ti gbagbo Gbekele yi o gba o Ah Gbekele oh Ah ah Gbekele se Uh uh uh uh uh uh uh Yi o gba o Omo igbagbo jowo teti ko gbo mi Mase beru mase fo'ya duro do'luwa Ko ma so hun to soro Fun baba loke Iwo sa ti ro Mo Jesu oooo Lazaru oku ojo merin Jesu ji dide Obinrin oni isun eje o fowo kan Jesu Nipa igbagbo to ni ori iwosan gba Ko ma so'hun to soro fun Jesu oooo Jesu n gbala Jesu n wo San Iwo sa ti gbagbo Gbekele ko ro mo Yi o wa pelu re Jesu n gbala Jesu n wo san Iwo sa ti gbagbo Gbekele yi o gba o Jesu n gbala Jesu n wo San Iwo sa ti gbagbo Gbekele ko ro mo Yi o wa pelu re Jesu n gbala Jesu n wo san Iwo sa ti gbagbo Gbekele yi o gba o Jesu n gbala Jesu n wo San Iwo sa ti gbagbo Gbekele ko ro mo Yi o wa pelu re Jesu n gbala Jesu n wo san Iwo sa ti gbagbo Gbekele yi o gba o Gbekele yi o gba o
Struggling with Gbekele? Become a better singer in 30 days with these videos!
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Gbekele Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 23 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/11336391/Jumoke+Omotoso/Gbekele>.
Discuss the Gbekele Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In