Song parody of

Solid Foundation

by Micho Ade

Here's where you get creative! Use our cool song parody creator to make a totally new musical idea and lyrics for the Solid Foundation song by Micho Ade.

Simply click on any word to get rhyming words suggestion to use instead of the original ones. You may also remove or alter entire lines if needed — when you're done save your work and share it with our community — have fun!

  • English (English)
  • Français (French)
  • Español (Spanish)

Solid foundation Solid foundation Iberu Oluwa ni ipinlese ogbon Eniba f'Oluwa bere to f'Oluwa saaju Lo kole sori apata Ile ti a ko sori iyanrin A ba yanrin lo Micho Ade Mo bere aye pelu iberu Olorun Mo bere ise mi pelu iberu Olorun Aye mi wa dabi ile ti a ko Ise mi wa dabi ile ti a ko Ti a ko sori apata to duro gbonin-gbonin Ipinlese to dara ni yo fa opin to dara Mase se tan koto roo ,koma baa dabamo Ronu nipa ojo ola ohun too fee se Solid foundation Baba lo ranmi nise si gbogbo omo Nigeria E teti kegbo Edumare lo ranmi nise si gbogbo omo africa E teti kegbo Pupo ninu wahala ode-oni lojepe Opo ninu wahala ode-oni lojepe Asise ojo kan latowo awon baba nla wa Tab'asise ojo kan latowo awon iya nla wa Lat'ojo pipe Eewo idile kan tabi eewo ilu Asa idile tabi taaso dasa ibile Egun idile tabi epe idile Egun ilu tabi epe ilu Oriki idile tabi tilu ati beebee lo Seb'ori enikan loti bere Koto dohun atiran-diran mofe kemo Iyen nipe , akoba tab'asise ojo kan Oleedi wahala aimoye odun Asise eeyan kan, O leedi wahala aimoye eniyan Anfani eeyan kan O leedi'gbadun egbegberun aimoye eniyan Toriinaa, mase setan koto roo, koma baa dabamo Ronu nipa ojo ola ohun too fee se Solid foundation Awon igbese aironu-jinle Opo leti ribi to yorisi Bibeeyan dasepo ati didowopo aironu-jinle Igbeyawo aironu-jinle Eto iselu aironu-jinle Eto isakoso aironu-jinle Ibere ore aironu-jinle Ibere ote aironu-jinle Koda, ibere ija aironujile Opolopo leti ribi to yorisi Gege bi apeere, isopo nigeria ni 1914 Iyen ni amagamation E wa wo bi to yorisi Ija oselu nile liberia ati ti seria-leone Ija esin nile Algeria S'eranti adehun Afonja, Afonja ilorin belu Alimi Fulani E wo ibere ajosepo Ife ati Moda'eke Ibere ajosepo Olu.ikere at'ogoga Fifagile ni 1993ati beebee lo Sebi gbogbo e leti ribi to yorisi Abamo kamase, asetan o daapon Torinaa, mase setan koto roo koma ba dabamo Ronu nipa ojo ola ohun toofee se Solid foundation Mase sohunkohun lairobiti yo yorisi Iwe adehun lofee towo bo Ronu ibiti yo yorisi Koda bo jadehun enu lofe beniyan se Ronu ibiti yo yorisi Koto beniyan sore tabi kegbe po Ronu ibiti yo yorisi Kooto gbani sile tabi gbani sise Ronu ibiti yo yorisi Imoran lofee gbani tab'ejo lo fe da Ronu ibiti yo yorisi Ija ibinu lofee beniyan ja Ronu ibiti yo yorisi Oro ibinu lofe so jade Ronu ibiti yo yorisi Oro asiri lofee so feeyan kan Ronu ibiti yo yorisi Ipade ote ni won pe e si Ronu ibiti yo yorisi Ero tabi igbese nla kan lo fe gbe Ronu ibiti yo yorisi Olugbowo tabi oniduro lofee se feeyan Ronu ibiti yo yorisi Ohunkohun yowu tobaa fee se Ronu ibiti yo yorisi O baa ronu ibiti yorisi kooto dawole Solid foundation

Done creating your parody?

Don't keep it to yourself! Save it now so you can share it with the rest of the world!

Quiz

Are you a music master?

»
How many members are there in pop group Little Mix?
A 3
B 4
C 5
D 2

Free, no signup required:

Add to Chrome

Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

Free, no signup required:

Add to Firefox

Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

Micho Ade tracks

On Radio Right Now

Loading...

Powered by OnRad.io