Song parody of

Oun Meta

by Oriyomi Kehinde

Here's where you get creative! Use our cool song parody creator to make a totally new musical idea and lyrics for the Oun Meta song by Oriyomi Kehinde.

Simply click on any word to get rhyming words suggestion to use instead of the original ones. You may also remove or alter entire lines if needed — when you're done save your work and share it with our community — have fun!

  • English (English)
  • Français (French)
  • Español (Spanish)

Interlude T reign on the mix Loun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire Oun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire Igba meta leda nnio Igba owuro, igba osan, ati àsálé tonje atunbotan eni Eda nji laye eda nwowo, eda ngbero ati bimo o Won gbagbe konwa atunbotan ire Oun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire Haa Eniyan tonsare ati lowo, eda kan tonsare ati lola Eniyan tongbero ati bimo o, towa nkemo lakebaje arami o Ko k'omo lesin bonse ngbaye Debi tan o kirun kofi ko won, o dagba o gbo tan ko s'agbara L'awon omo ba nta ile mo baba lori, béè mani won tun gbemi arawon Egbo se iyen j'atunbotan ire? Atunbotan nile aye matun kere, si igba teda ba palemo laye, t'eda ba ba ara e nile ikeyin Ni sàréè ile ifúnpínpín Ibi tio s'áyè ati wamo, koni sowo koni s'omo, ile teda ko laye o ni simo Nkan marun pere ma nan o bere, k'olohun dakun je kale sàséyégé Maje k'eśu kan o takomi olohun, dakun jen latunbotan ire Oun meta leda nwa o Eda nw'owo eda nw'omo Eda nwa atubotan ire Nkan marun tiwon o bere: talolohun re tal'ojise? kioesin re nibo l'adojuko? Man kitaabuka kini tírà? Tao ba komo lesin Olohun Nje a fe ko latunbotan're Oun meta leda nwa o Eda nw'owo eda nw'omo Eda nwa atubotan ire Irawo mi jeko tan titi dale amin Irawo mi jeko tan titi dale amin Ebun to funmi oyato si tenikanlan Osemi lakanda eyan laye timowa, eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Irawo miii Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Mashaallah Allahumma anfaany bima alamtany, wa alimny ma ynafauny warzuqny Ilima yanfaunny amina aamin Sore funmi lori imo to funmi yah Allah Kosi fiyemi bi yio se tun sanfani funmi Eyi tofunmi sha lebun timofi nse bebe Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Allah To be talented lowo olohun loti nwa, ebun mani latorun ki eda towaye Ale kose carpenter abi ka kose fashion Mechanical engineer pelu electrician Ale fe je sailor fun oko oju omi Ale fe di pilot awako ofurufu o Kosenikan laye naa tole ko ise orin Af'eni olohun bafun lebun tofe mo bi yiose lo Yio mase elegbe leyin toba ya a daduro Orin to funmi sha lebun timofi nse bebe Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Ise owo mi koma dami láàmu allah, masemi nise lari o tio ma r'owo yo Masemi lalasedanu tio ni akojo Masemi lolokiki kan tio wulo fun ebi fara Gbemi lati superstar kin tun wadi mega Won lokiki p'ona meji kosetemi nire Kon tarami rise owo e konfi iru e toro, Ebun to funmio Ebun to funmi yah robbi kotomi se bebe Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe Semi loore ooo Semi loore tikoni yi sibanuje Awon omo mi, sewon ni alalubarika, Awon to j'ako, mase je kiwon di ipata Awon to je abo, konma ma gbe igba iranu K'obami o sewon lelesin kiwon ma sesin rara Sewon lologo kawon omo mi mama ya agan Awa ti abiwon konma riwa ribanuje Kodawa lola yah robbi kotowa sebebe Irawo mi jeko tan titi dale ami Ebun to funmi oyato si tenikankan Osemi lakanda eyan laye timowa Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe O to lope taloni koto lope? Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo o, ope loye O to lope taloni koto lope? Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo o, ope loye Oke aimoye loti file sasobora tiwon tiku ao fi yowon, ope ni emi finda Emi o runpa kilemi o ni dupe fun o Mio waye asan kilemi oni maayo si? Alhamdulillahi mo r'ope yen da Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo ope loye O to lope taloni koto lope? Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo o, ope loye Abdul lateef kehinde emi rope da o Wallahi, mo moore olohun lemi finso Dupe eyi kotun gbamiran lolohun wi Atipe ilopo ilopo lore naa a tunje Oremi dupe maso pe kotope rara o Boselewu kori laye iru e lawon kan nwa Oba lo pon e le koje ko toshi o dupe Ma f'ope sile laida ope loye O to lope taloni koto lope? Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo o, ope loye Igba aini won niyen o lo titi, toripe Leyin òdá ojo a ro toba ya Oun tenikan nbinu o wipe o kere Oun mani enikan ri, tondupe adamojumo Ha Ore olohun lorimi o kere rara o Aanu e layemi o kèrémí ko o Ko famiseyin lawujo o, ope loye O to lope taloni koto lope? Oba to ponmile pelu ebun mi o tope Ko yomi seyin lawujo o, ope loye Allah Maje kin nwaye inira adaniwaye o Maje kin nwaye inira, adanwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Maje kin nwaye inira adaniwaye o Maje kin nwaye inira, adanwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Maje kin nwaye inira adaniwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Maje kin nwaye inira adaniwaye o, igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini, bi t'odèé aramide mi ganiya Dida oruko alatileyin mi Alhaja ganeeyat aramide biola alaka, tesiwaju Maje kin nwaye inira adaniwaye o Maje kin nwaye inira, adanwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Dida oruko alatileyin mi Alhaja ganeeyat aramide biola alaka tesiwaju Maje kin nwaye inira adaniwaye o Maje kin nwaye inira, adanwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Dida oruko alatileyin mi Alhaja ganeeyat aramide biola alaka, tesiwaju Maje kin nwaye inira adaniwaye o Maje kin nwaye inira, adanwaye o Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe Isemi ayemi ko tutu minimini Bi t'odèé aramide mi ganiya Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye Kase emi imoore, katun gbore alekun laye Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye Kase emi imoore, katun gbore alekun laye Dida oruko oloore mi Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye Kase emi imoore, katun gbore alekun laye Dida oruko oloore mi Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore, awa t'olohun ba ran iru eda bayen si, kasaponle e B'obaseto ati b'oseye Kase emi imoore, katun gbore alekun laye Dida oruko oloore mi Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye Kase emi imoore, katun gbore alekun laye Alhaji latifu kokonbilo, billooo Àjéyè kokonbilo, bilooo Adigun ti shaproper tipe Awon ota e wa nsare lasan Alhaji latifu kokonbilo, billooo Àjéyè kokonbilo, bilooo Adigun ti shaproper tipe Awon ota e wa nsare lasan Dida oruko alatileyin mi Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju Alhaji latifu kokonbilo, billooo Àjéyè kokonbilo, bilooo Adigun ti shaproper tipe Awon ota e wa nsare lasan Dida oruko alatileyin mi Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju Pataki toje, seleyi o to l'apere ni? Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da Awon eyan tomo, totimo Lofin nmo koko Pataki toje seleyi o to lapere ni Dida oruko alatileyin mi Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju Pataki toje, seleyi o to l'apere ni? Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da Awon eyan tomo, totimo Lofin nmo koko Pataki toje seleyi o to lapere ni Dida oruko alatileyin mi Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju Pataki toje, seleyi o to l'apere ni? Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da Awon eyan tomo, totimo Lofin nmo koko Pataki toje seleyi o to lapere ni Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu Osu mesan ninu oyun o wa saye Ojo ti abi e ta lo

Done creating your parody?

Don't keep it to yourself! Save it now so you can share it with the rest of the world!

Browse Lyrics.com

Quiz

Are you a music master?

»
David Coverdale is the founding member and vocalist of which band?
A Journey
B Motley Crüe
C Def Leppard
D Whitesnake

Free, no signup required:

Add to Chrome

Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

Free, no signup required:

Add to Firefox

Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

Oriyomi Kehinde tracks

On Radio Right Now

Loading...

Powered by OnRad.io


Think you know music? Test your MusicIQ here!