Anu

Hibeekay

0 fans

Hibeekay


 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Kosi ohun ti mo le se
Lai si iranlowo re baba
Ayeraye ma wo mi niran jowo dasi oro aye mi
Ki anu re fohun ki gbogbo idawole mi ma yori si rere
Bi orun ba si fun mi
Ase irorun ohun lo ma tele
Adura a ma gba alubarika a wole ise a mu ere wa
Ire lotun ire losi laye eyan orin ope a tun yo

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Oro re fi yewa, iwo yio sanu fun eniti iwo o sanu fun
Eyonu re yio wa lori eniti iwo ba yonu si laye ati ni orun
Baba jowo je n nipin ninu eyonu re
Kin se nipa adura, abi iwa mimo abi eto bikose nipa ore ofe ati orire
Aye mi nilo ore ofe ati orire lati odo re baba mi
Kanu re joba laye mi ati ohun gbogbo to jemo temi

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o, jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo
Oro ayo mi, ma jeko pamilekun

Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o, jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo
Oro ayo mi, ma jeko pamilekun

Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o, jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo
Oro ayo mi, ma jeko pamilekun

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
(Till fade)

 Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer

Written by: Awoyomi Oluwabukunmi

Lyrics © Hibeekay

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Anu Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Anu Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 10 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8731852/Hibeekay/Anu>.

    Missing lyrics by Hibeekay?

    Know any other songs by Hibeekay? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    "Oh, the sound of Christmas coming to town, Fills the air like snow falling all around..."
    A Africa
    B The Sound of Christmas
    C Bigger Than The Universe
    D Game Over

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Hibeekay tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!