Oba Awon Oba

Hibeekay, Akin Omo Akin, Omobadeji

0 fans

Hibeekay


25 

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Omobadeji: 
Kabiyesi Olodumare ekun oko oke pharaoh 
Oba nla ti nfi oba je, 
Oba to ju oba lo, Oba awon oba 
Aterere kari aye, atorise, ameda aweda aseda 
Emi o to lati yin o o, Olorun awon baba wa 
Ti nje emi ni, emi ni, emi ni Mo ke Kabiyesi o, 
Oba awon oba, Oba awon oba Oba awon oba, Oba awon oba 
All: Oba awon oba, Oba awon oba Till fade.......

Hibeekay: 
Tani eni ti o ba esu wi 
To da aye ati orun 
Gbongbo idile jese 
Akobi ninu awon oku 
Kiniu eya juda 
Apata ayeraye 
Ologo didan ni 
Kabio osi Olorun 
Olowogbogboro ni
Ti nyo omo re lofin aye 
Alagbada ina 
Oba ayeraye 
Oba ti o la omi okun pupa 
To gba omo Israeli 
Lowo ogun pharaoh 
Awon ara egipti 
Oba to ju oba lo 
Ibeere ati opin 
Olorun Abraham 
Olorun Isaaki 
Olorun Jakobu 
Olorun Dafidi 

Akin Omo Akin: 
Oba aja bi iji 
Olorun ailopin 
Agbafefe sola 
Pari pari aye 
Eni mimo ola 
Onibudo eye 
Aara wawa nwowoo 
Pitu pitu ola 
Adakeroro seun lile 
Oba akoda aye 
Oba aseda orun 
Akiikitan Ayiinyintan 
Iwo naa ni 
Oba tole logun 
Mimo mimo mimo 
Eleburu ike 
Oba onibu ola 
Oba onibu ore 
Akasebijo bawon wi 
Ipa lori ipa 
Abani dinbe lai jeran 
Ajanaku ode orun 
Weli weli bi ejiinpani 
Funfun nini lode orun 
Akobi akorii 
Ako oju tole logun 
Oba aseyi to fe 
Asegun ma lo ibon 
Oke ninu ogbun 
Odaada tii ri da 
Odaada tii ri da 
Dagi lekun esoo 
Agba ninu eko 
Onibudo eye 
Aboni ma jeun 
Afuye bi ewe 
Awuwo bi erin 
Kabiyesi ode orun 
Afoba joba 
Ganaku bi oyun 
Gulutu bi omo 
Agbekumi ma bi 
Olori oloore 
Gboun gboun bi owuu lurin 
Akeni bi oju
Atoni bi omo 
Kosoba bi ire 
Aponni ma gba oja 
Asoni ma sun lo 
Oba ayeraye 
Titi lae lae lae lae lae lae lae lae lae ni un o ma yin o nigbagbogbo...

 Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer

Written by: Awoyomi Oluwabukunmi, Akin Omo Akin

Lyrics © Hibeekay

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Oba Awon Oba Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Oba Awon Oba Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 9 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8731851/Hibeekay/Oba+Awon+Oba>.

    Missing lyrics by Hibeekay?

    Know any other songs by Hibeekay? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    Rockstar David Howell Evans is better known by what name?
    A The Purge
    B The Serge
    C The Verge
    D The Edge

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Hibeekay tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!