Osuba (Call to Prayer)
Thetimo
Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!
Ah ah ah ah ah ah Osuba re re Osuba re re o o Osuba re re o o Osuba re re o o Olori aiye Oba to laiye Olori orun Oba to l'orun You are the sounding of the waters You're the droplets of the rain Mo juba re, f'oribale All creations speak Your glory Sky, the deep, the firmament Won juba fun Oba to d'ohun gbogbo Osuba re re o Ah ah ah ah ah Osuba re re o Ah ah ah ah ah Osuba re re o Ah ah ah ah ah Osuba re re o Ah ah ah ah ah Bi a ba s'eni l'oore, ope la nda o Oba mi alagbala nla Eti kan agbogbo aiye Olugbo orun ti ngbo t'iye t'omo Gb'oteranko, gbo t'eye, gbo t'eja inu odo Baba am'oyun igbin ninu ikarawun Om'akuko 'diye ninu eyin Am'ofun m'edo El'eti gborogbodo oro ki'ikun Abeti lu k'ara k'ara, lu k'ara, lu k'ara bi ajere Baba mi ti ngbo adura Ehhhheh Ti mba ti nbere, Oun se temi Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo Ti mba ti nbere, Oun se temi Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo Ti mba ti nbere, Oun se temi Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo Ti mba ti nbere, Oun jemi ni O Ti mba ti nbere, Oun se temi Oba to nje mi, ni gb'esan gb'ewa o Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo Ti mba ti nbere, l'oruko Jesu Ti mba ti nbere, Oun se temi Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo
Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Osuba (Call to Prayer) Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 3 Jun 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8359911/Thetimo/Osuba+%28Call+to+Prayer%29>.
Discuss the Osuba (Call to Prayer) Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In