Shayo

Vinnyyio

0 fans

Vinnyyio


3:07

 Struggling with Shayo? Become a better singer in 30 days with these videos!

Yeah eeeeh
Kigi toda, ẹyẹ ti fo
Ole l'everybody ẹni ilẹ mọ ni Barawo
Kilo gbe yi jẹ Kin Yẹwo
Owo Ọmọ Alafia pẹlu Ṣayo
Kigi toda, ẹyẹ ti fo
Ole l'everybody ẹni ilẹ mọ ni Barawo
Kilo gbe yi jẹ Kin Yẹwo
Owo Ọmọ Alafia pẹlu Ṣayo
Hello Sir ṣẹma gbọ nkan ti mo fẹ sọ bai
Many things lo ti ẹ n ṣẹlẹ laye tawa bai
Awọn eyan,wọn tun wa kora wọn ni ijanu bai
Wọn reti rapture bi wipe wọn reti iyanu bai
Bole dogun bo dogun, bole dija Bodija
Abẹrẹ five naira sọnu, wọn ma f'ogun 5k wa
Pata ọmọ tan ba fẹ lo, ti o ba ṣe ja wọn fẹyin ja
So baba 72, fẹ ma jẹṣẹ ọmọ 22
Ọmọ to fine to youngin to dẹ ṣi lẹjẹ tutu
Kẹma lọ ma wadi kiri nigba ti baba ba ku
Wọn ni baba ku baba ku
O ti gọ o tin Sun
Aimọye baba to ti ku ti o si baba to ku
Kigi toda, ẹyẹ ti fo
Ole l'everybody ẹni ilẹ mọ ni Barawo
Kilo gbe yi jẹ Kin Yẹwo
Owo Ọmọ Alafia pẹlu Ṣayo
O lọmọ kan she no dy ride dirty
Fawọn broke niggas
O lorukọ kan tan ma n pe wọn tun ma n pe n Gold Digger
O ni kan ni kan ni
O un nikan lan fẹ fọ
O ti lọ oke okun ẹ feti silẹ Sangba fọ
Ọmọ naija ti o like naira o like Dollar
Ko hi ti lowo motor buh o rowo ranṣẹ pe uber
Account ẹ o le wọ red (NO)
She no dy give you a F
Sadist ni ,She no dy give chance
She dy write Herstory
Small body big engine body to naya toyin
Ọjọ toma ṣẹlẹ bai ko ye ẹ she pull d trigger
O ṣẹ de lati yankee ni bi two weeks later
Friday lalẹ ọjọ na men, it is too Brutal
So o ni bọbọ kan to ma n wa wa LoverBoy
O ti sọ fun many times koye ma wa o un wale mọ
He no dy listen, he dy deaf
Alakọri ẹ o kin gbẹfff
O kan lẹkun kokoko ọmọ wa nle to n Jogodo
she no open on a norm
Buh dis night she just Open
Ṣilẹ kun fun ko wọle lo ju ẹsẹ lock am back
Okay ki lẹ n wa sir
I just wan express my feelings
Iyẹn na koba yin sir
You have to die this night
Ko sọrọ ju o fa bọn yọ
Oya kawọ soke
Kodiju ko kunlẹ pẹlu orukun mejeji
Com pull am for her wall
Come tell am say wo giri yẹn ṣori bo ṣe ya palẹ
Next time to ba ri mi o ma better Ko wọlẹ

 Struggling with Shayo? Become a better singer in 30 days with these videos!

Written by: Adeyemi Olofintuyi

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Shayo Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Shayo Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 29 Apr. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/10635360/Vinnyyio/Shayo>.

    Missing lyrics by Vinnyyio?

    Know any other songs by Vinnyyio? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    Will.i.am is best known for performing with which hip hop group?
    A The Black Eyed Peas
    B N.W.A.
    C CunninLynguists
    D LMFAO

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Vinnyyio tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!